Omidan Joy Raimi Mojisola, ti gba ade Omidan Agbaye Naijriia fun ti ọdun 2025. Joy, ẹni ọdun mẹrinlelogun (24) to ṣoju ipinlẹ Osun, gbegba oroke nibi idije naa to waye ni Victoria Island, ipinlẹ Eko ...
Kii ṣe wahala ati idaamu kekere ni arẹwa obinrin arinrin oge, Chidinma Adetshina, ko to ṣe ipo krji ninu idije Miss Universe 2024. Idije Miss Universe ni wọn ti n yan omidan to rẹwa julọ ni agbaye.